Mojim 歌詞
Mojim 歌詞 > 欧州米国の歌手 > Asa > Bed Of Stone > Grateful

Asa



歌詞
アルバムリスト

Asa

Grateful

Era ile, era ile
Won yin baba l'oke
Yanrin okun, yanrin okun
Won n yin baba l'oke
Eranko ile, eranko igbo Won n yin baba l'oke
もっと沢山の歌詞は ※ Mojim.com
Awon alaini, awon tan ti ni
Won yin baba l'oke

[Chorus:]
Ko se igbati nkan ba se yan
Ko to mo pe baba n be l'oke
Ko se igbati nkan ba se yan
Ko to mo pe looto o n be l'oke
You don't have to wait till you feel the pain
You can start right now
It's not too late
It's not too late, to be grateful

Era ile, era ile,
Won yin baba l'oke
Yanrin okun, yanrin okun
Won yin baba l'oke
Pe mo wa laye, mo wa laye
Gbogbo n ti mo ni, ma fin yi o l'ogo
Believe this world a better place

[Chorus]

Wo mi, bi mo se n f'ope ye baba
Da di da dada
Da di da dudu
Da di da dada
Da di da dudu
It's not too laaate